Home Search Countries Albums
Read en Translation

Casablanca Lyrics


Ṣe l'ọn pe mi n zaddy

Mo ni "baby what's popping

Girl I'm chasing money

Ọrọ owo yẹn ṣa lo ba mi

If I no press you money that one no mean say I stingy

As ọmọ ọgbọn mo calcu k'owo ma lọ tan lọwọ mi

Casablanca mo wọ sọrun, mhen I'm looking fresh and classy

Amiri ṣa mo wọ soju, k'aṣiri ma lọ tu

Mo ni Balenciaga mo wọ sẹsẹ, original no be Fugazzi

One million dollar no do me

Ọmọ aye hustle lọ

But mo ni Casablanca mo wọ sọrun, mhen I'm looking fresh and classy

Amiri ṣa mo wọ soju, k'aṣiri ma lọ tu

Mo ni Balenciaga mo wọ sẹsẹ, original no be Fugazzi

One million dollar no do me

Ọmọ aye hustle lọ, hustle lọ

Vanilla Bottega, Vanilla Bottega

With some Lil Kesh

O le jẹ dollar

O le jẹ naira, awa maa nawo o

Ibi re la ma sọ gba si

K'ọmọ owo to gba CC

Nothing wey I never see

A fowo mọti i ku s'ode

So, mo fi Azul to'le

Oniyangi kuro lọna mi

Ṣo mọ nnkan to wa lọkan mi

Ah ah, steeze no go kill me

Valentino lori mi

Fendi lẹsẹ rẹ

O le ku nitori mi

I blow hiroshima nagasaki

Ba mi ṣẹ dollar Rasaki

Balenciaga lọrun mi

When I dey hustle ṣo ri mi?

Casablanca mo wọ sọrun, mhen I'm looking fresh and classy

Amiri ṣa mo wọ soju, k'aṣiri ma lọ tu

Mo ni Balenciaga mo wọ sẹsẹ, original no be Fugazzi

One million dollar no do me

Ọmọ aye hustle lọ

But mo ni Casablanca mo wọ sọrun, mhen I'm looking fresh and classy

Amiri ṣa mo wọ soju, k'aṣiri ma lọ tu

Mo ni Balenciaga mo wọ sẹsẹ, original no be Fugazzi

One million dollar no do me

Ọmọ aye hustle lọ, hustle lọ

K'aṣiri ma lọ tu

Original no be Fugazzi

Ọmọ aye hustle lọ, hustle lọ

Enjoy Synced Lyrics With Our Mobile App

Download on Google PlayGet it on App Store

WATCH VIDEO

ABOUT THIS SONG


Release Year : 2024


Album : (Single)


Added By : Farida

SEE ALSO

AUTHOR

Shoday

Nigeria

...

YOU MAY ALSO LIKE