New Taker Lyrics

Gangster ni mo ṣa n ṣe ti mo pade Mufu
I'm rolling with some rich thugs eeyan Ikechuckwu
Ṣo mọ nnkan toju ri ki n to gba muscle ni
Ori gbona ninu dread lock mi o le sun mọju
Mummy mi o ṣa mọ pọmọ yii ti kobo
Ngbọ wọn ni po la ẹbu pẹlu ogo goro
Ẹ sa ma tẹle mi ẹyin janmọ mi
Dewale Anọbi lo n bọ, yeah
Igba lo yi awọn kan ti hot nigba kan
Sọ fun new take yẹn ko ṣọra gidi gan-an
Cos the road to success e dey hard gidi gan-an
And e easy to dey fall
To ba dẹ ti lowo raṣọ sara gidi gan-an
Ko wọ off thug ati zanku to the world
If you kpai yourself ọmọ life no go stop
Jẹun sara gidi gan-an
Eni tere o
Eji tere mo ni ibeere o
Ṣo yẹ kajẹpako ma wa sunle o
O lọ n fọwọ osi lọ juwee ile o
Ti n ba sọrọ wọn a ni mo tun ti de o
Ọlọba ice ati kurube o
Yankee ti ji tipẹ, o ti n runle o
Show working ma pe mi pe ki n wa ja
Owo ni ko pe mi fun
No dey whine yourself nigga
You dream so bigger
Focus on my grind cos I no like fipa
You suppose get sense if you no get helper
Wọn fẹ mọku to pa iya teacher, ẹ le bi Ifa
Igba lo yi awọn kan ti hot nigba kan
Sọ fun new take yẹn ko ṣọra gidi gan-an
Cos the road to success e dey hard gidi gan-an
And e easy to dey fall
To ba dẹ ti lowo raṣọ sara gidi gan-an
Ko wọ off thug ati zanku to the world
If you kpai yourself ọmọ life no go stop
Eni tere o
Eji tere mo ni ibeere o
Ṣo yẹ kajẹpako ma wa sunle o
O lọ n fọwọ osi lọ juwee ile o
Ti n ba sọrọ wọn a ni mo tun ti de o
Ọlọba ice ati kurube o
Yankee ti ji tipẹ, o ti n runle o
Show working ma pe mi pe ki n wa ja
Owo ni ko pe mi fun
Jẹun sara gidi gan-an
WATCH VIDEO
ABOUT THIS SONG
Release Year : 2025
Album : (Single)
Copyright : © 2025 Tobisneh records / Dapper Music & Ent, Under exclusive license to Dvpper Digital Ltd.
Added By : Farida
SEE ALSO
AUTHOR
YOU MAY ALSO LIKE