Oba Alaanu Mi Lyrics

Gbogbo aye mi ni nwo Fi yin o
Gbogbo Ile mi la o ma yin o
Orin ope re oluwa titi Lai ni lenu mi o o
Oba alanu mi o
Gbogbo aye mi ni nwo Fi yin o
Gbogbo Ile mi la o ma yin o
Orin ope re oluwa titi Lai ni lenu mi o o
Oba alanu mi o
Modupe o o
Mori Anu gba
Opo loti ku ti won to Fi le sasobora
Emi erupe lasan to se leniyan
Oba alanu mi o
Modupe o o
Mori Anu gba
Opo loti ku ti won to Fi le sasobora
Emi erupe lasan to se leniyan
Oba alanu mi o
Gbogbo aye mi ni nwo Fi yin o
Gbogbo Ile mi la o ma yin o
Orin ope re oluwa titi Lai ni lenu mi o o
Oba alanu mi o
Gbogbo aye mi ni nwo Fi yin o
Gbogbo Ile mi la o ma yin o
Orin ope re oluwa titi Lai ni lenu mi o o
Oba alanu mi o
Modupe o o
Mori Anu gba
Opo loti ku ti won to Fi le sasobora
Emi erupe lasan to se leniyan
Oba alanu mi o
Ninu lala ati rogbodiyan aye
Oba to ni kokoro to n ti to n si lo ntoju mi
Ki ma ise mimo se mi o
Ife Jesu ni kalfari lo so mi d'omo
If I have many tongues
To sing your praise
Won't be enough compared to your goodness running after me
You gave me everything though I don't deserve it
Oba alanu mi
Gbogbo aye mi ni nwo Fi yin o
Gbogbo Ile mi la o ma yin o
Orin ope re oluwa titi Lai ni lenu mi o o
Oba alanu mi o
Gbogbo aye mi ni nwo Fi yin o
Gbogbo Ile mi la o ma yin o
Orin ope re oluwa titi Lai ni lenu mi o o
Oba alanu mi o
Modupe o o
Mori Anu GBA
Opo loti ku ti won to Fi le sasobora
Emi erupe lasan to se leniyan
Oba alanu mi o
Modupe o o
Mori Anu GBA
Opo loti ku ti won to Fi le sasobora
Emi erupe lasan to se leniyan
Oba alanu mi o
WATCH VIDEO
ABOUT THIS SONG
Release Year : 2022
Album : Oba Alaanu Mi (Single)
Added By : Farida
SEE ALSO
AUTHOR
YOU MAY ALSO LIKE