Home Search Countries Albums

Tèmi Ni Tèmi

BRYMO

Tèmi Ni Tèmi Lyrics


Ife mi dariji mi
Omode n se mi
Afarawe O se temi
Ka daduro ni mo wari
Moti so tele tele ri
Igboro O ma rerin ri
Ijakadi lo mu nise
Karohunwi O bopo sise

Bi nba fa wa n’ole
Bi nba tule wan’loro
Bi n duro won ma mere
Bi nba sa wa ni mo kere
Aba lo aba bo
B’ohun won ko para won oh
Ohun A ni la n nani
Temi Ni Temi

Awelewa forijimi
Mo lakaka kin to de bi
Riro mede O se temi
Nibi lile la n b’okunrin
Ife re sha lo’n duro timi
O dudu, O funfun, O Pupa
Ife re sha lo’n munu tumi
Ninu erun at’ojo atilera

Bi nba fa wa n’ole
Bi nba tule wan’loro
Bi n duro won ma mere
Bi nba sa wa ni mo kere
Aba lo aba bo
B’ohun won ko para won oh
Ohun A ni la n nani
Temi Ni Temi

Aba lo aba bo
Temi loje lale eni oh
Gbogbo igba ti o ba lo
Mo mo pe o pada wa

Enjoy Synced Lyrics With Our Mobile App

Download on Google PlayGet it on App Store

WATCH VIDEO

ABOUT THIS SONG


Release Year : 2021


Album : Tèmi Ni Tèmi (Single)


Added By : Farida

SEE ALSO

AUTHOR

BRYMO

Nigeria

Brymo is a musician, Songwriter, Performing/Recording and Poet. ...

YOU MAY ALSO LIKE