Méji Méji Lyrics
Mofiye fo mo rire
Mowaju mowoke Ire de
Kijo mole motun taka sufe
O dun mo mi o
O dun mo mi o
O dun mo mi o
O dun mo mi o
Meji Meji ladaye oh (Meji Meji ladaye o)
Ife re simi O jin gan gan (Meji Meji ladaye o)
Meji Meji ladaye oh (Meji Meji ladaye o)
Ife re simi O jin gan gan (Meji Meji ladaye o)
Ore dakun ro koto lo
Motaraka mo subu
Ki n to ko ohun mo n so
Yara gboro, Lora fesi
Esin o gbani Iwa o Lani
Ohun to wun ni lo n wani
Ore dakun ro koto lo
Motaraka mo subu
Ki n to mo ohun mo n so
Yara gboro lora fesi
Esin o gbani Iwa o lani
Ohun to wun ni lo n wani
Mofiye fo mo rire
Mowaju mowoke Ire de
Kijo mole motun taka sufe
O dun mo mi o
O dun mo mi o
O dun mo mi o
O dun mo mi o
Meji Meji ladayе oh (Meji Meji ladaye o)
Ifе re simi O jin gan gan (Meji Meji ladaye o)
Meji Meji ladaye oh (Meji Meji ladaye o)
Ife re simi O jin gan gan (Meji Meji ladaye o)
Meji Meji ladaye oh (Meji Meji ladaye o)
Ife re simi O jin gan gan (Meji Meji ladaye o)
Meji Meji ladaye oh (Meji Meji ladaye o)
Ife re simi O jin gan gan (Meji Meji ladaye o)
WATCH VIDEO
ABOUT THIS SONG
Release Year : 2021
Album : Méji Méji (Single)
Added By : Farida
SEE ALSO
AUTHOR
YOU MAY ALSO LIKE