Alelùyà Méje Lyrics
Aleluya méje méje
Oselu pejo fun ojo méje
Won fe to’lu lojo méje
Gbogbo isele korin kese
Aleluya meje méje
Awon ojelu fere ge
Won l’awon omo epa tun tide
Won fe darulu mere le
Aleluya méje méje
Akoni leru won tun ti de
Won fe so bose mama gbe
Iwo n foku sorun O n sise agbе
Gbogbo isele korin kesе
Won l’awon omidan lo maye le
Won fe jeka won fe roso
Oko loma ye okunrin le
Bo kowaju si e kota
Boba keyin si e kota
Boba kuwo nikan se hun o le se
Ma gbagbe ibi o ti babo
Bo kowaju si e kota
Boba keyin si e kota
Boba kuwo nikan se hun o le se
Ma gbagbe ibi o ti babo
Aleluya méje méje (Arere epa epa)
Adaleru won tun ti de (Arere epa epa)
Ko fe k’omo o mo baba re (Arere epa epa)
Ko fe k’oko ko gbo t’aya re (Arere epa epa)
Gbogbo isele korin kese (Arere epa epa)
Won l’awon omidan lo maye le (Arere epa epa)
Won fe jeka won fe roso (Arere epa epa)
Oko loma ye okunrin le (Arere epa epa)
WATCH VIDEO
ABOUT THIS SONG
Release Year : 2021
Album : Èsan (Album)
Added By : Farida
SEE ALSO
AUTHOR
YOU MAY ALSO LIKE