Fuji Vibe Lyrics
O ti pọ gan-an
Gan-an, gan-an, gan-an
Ẹ ma fi agilinti wọbọ o, kẹ ma fi were we mi
Ẹni ba lọ lo le mọ a bọ le ṣalaye ni
Awọn ọmọ better ti pọ
Keep your money to ba n bọ
Lokeloke la ma lọ, ẹ ri pe Balenciaga yẹn yatọ
Baby wa uhn uhn, mi o raye k'eeyan fẹran kan jẹun
Oje lo jẹ uhn uhn, ko n ṣe iwọ nikan ẹgbẹẹgbẹrun
Haba! Vanessa ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju
Ye, is a mental
O lowo o lọ n loyun
Ah sukerike rike bumbum
Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan
Super extravagance lọmọ
Emi l'Asake medo t'ọn sọ
Baby you catch my feelings ahn ahn
I'm getting bigger
You dey shack my head like gbana
This your booty are you from Ghana?
Ọmọ olo mi ka ma nawọ ya, ma ṣe jẹ k'ọn mọ
This your booty fit to jawaya, o ga de sanmọ
Ibadi yẹn fẹ ki n ṣe wire into your aza
Ọmọ olo mi ye ma gaza
No pressure, wọn da mọ ọga Ade ẹni lọ lo bọ
Wọ America lọ fun tour
Akata wọn pọ lọpọ
Plenty plenty ọmọge
Wọn fẹ jẹ ki n sa nile
Ori mi lo yọ mi, ọta i ba yọ mi
Ọmọ ọpẹ I dey find my way
Make bad belle no come stop my reign
Bẹbẹ n lọ like a moving train
Fun mi ni big big money no chicken change
Owo n bọ, ọla n bọ, alaafia ati igbadun n bọ
I no wan talk plenty talk my record can back it up
La-do-re-mi-fa-mi-so-la
Oluwa ni ṣọla
Yarinya
Haba! Vanessa ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju
Ye, is a mental
O lowo o lọ n loyun
Ah sukerike rike bumbum
Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan
Super extravagance lọmọ
Emi l'Asake medo t'ọn sọ
Baby you catch my feelings ahn ahn
I'm getting bigger
You dey shack my head like gbana
This your booty are you from Ghana?
Ọmọ olo mi ka ma nawọ ya, ma ṣe jẹ k'ọn mọ
This your booty fit to jawaya, o ga de sanmọ
Ibadi yẹn fẹ ki n ṣe wire into your aza
Ọmọ olo mi ye ma gaza
Mr Money, Money dance, Mr Money
Money dance, Mr Money, Money dance
Mr Money, Money dance, Mr Money
Money dance, Mr Money, Money dance
Mr Money, Money dance, Mr Money
Money dance
WATCH VIDEO
ABOUT THIS SONG
Release Year : 2024
Album : (Single)
Copyright : © 2024 YBNL Nation / EMPIRE
Added By : Farida
SEE ALSO
AUTHOR
YOU MAY ALSO LIKE